Sáàmù 115:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀ yin tí ó bẹ̀rù Olúwa, gbẹ́kẹ̀lé Olúwa:oun ní ìrànwọ́ àti ààbò wọn.

Sáàmù 115

Sáàmù 115:2-16