Sáàmù 113:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó gbé òtòsì dìde láti inú erùpẹ̀, àti péó gbé aláìní sókè láti inú ààtàn wá.

Sáàmù 113

Sáàmù 113:1-9