Sáàmù 112:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun kì yóò bèèrè ìyìn búburú:ọkàn Rẹ̀ ti dúró, ó ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Olúwa.

Sáàmù 112

Sáàmù 112:1-10