Sáàmù 111:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ máa yin Olúwa. Èmi yóò máayìn Olúwa pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi,ní àwujọ àwọn olóòtọ́, àti ní ijọ ènìyàn.

Sáàmù 111

Sáàmù 111:1-10