Sáàmù 110:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò ṣe ìdájọ́ láàrin kènfèrí,yóò kún ibùgbé wọn pẹ̀lú òkú ara;yóò fọ́n àwọn olórí ká sí orí ilẹ̀ ayé tí ó gbòòrò.

Sáàmù 110

Sáàmù 110:1-7