Sáàmù 110:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sọ fún Olúwa mi, pé ìwọ jòkòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi, títí èmi yóò fi sọ àwọn ọ̀tá Rẹ̀ di àpótí ìtisẹ̀ Rẹ

Sáàmù 110

Sáàmù 110:1-5