Sáàmù 109:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí a gé àrọ́mọdọ́mọ Rẹ̀ kúròkí orúkọ wọn kí ó parẹ́ ní ìran tí ń bọ̀

Sáàmù 109

Sáàmù 109:10-15