Sáàmù 108:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbé ara Rẹ ga, Ọlọ́run, lórí àwọn ọ̀run,àti ògo Rẹ lórí gbogbo ayé.

Sáàmù 108

Sáàmù 108:1-10