Sáàmù 107:42-43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

42. Àwọn tí ó dúró sì ríi, inú wọn sì dùnṣùgbọ́n gbogbo olùṣe búburú yóò pa ẹnu Rẹ̀ mọ́.

43. Ẹni tí ó bá gbọ́n, jẹ́ kí ó kíyèsí nǹkan wọ̀nyíkí ó wo títóbi ìfẹ́ Olúwa.

Sáàmù 107