Sáàmù 107:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó bùkún wọn, wọ́n sì pọ̀ sí i ní iyekò sí jẹ́ kí ẹran ọ̀sìn wọn kí ó dín kù.

Sáàmù 107

Sáàmù 107:28-43