Sáàmù 106:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn baba wa wà ní Éjíbítìiṣẹ́ ìyanu Rẹ kò yé wọnwọn kò rántí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àánú Rẹgẹ́gẹ́ bí wọn ṣe sọ̀tẹ̀ sí ọ níbi òkun, àní nibi òkun pupa

Sáàmù 106

Sáàmù 106:1-17