Sáàmù 106:47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbà wá, Olúwa Ọlọ́run wa,kí o sì ṣà wá jọ kúrò láàrin àwọn aláìkọlàláti máa fí ọpẹ́ fún orúkọ mímọ́ Rẹláti máa ṣògo nínú ìyìn Rẹ.

Sáàmù 106

Sáàmù 106:37-48