Sáàmù 106:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì fà wọ́n lé àwọn orílẹ̀ èdè lọ́wọ́,àwọn ọ̀tá wọn sì jọba lórí wọn.

Sáàmù 106

Sáàmù 106:32-45