Sáàmù 106:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀.Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọkùnrin àti àwọnọmọbìnrin wọn.Wọn fi wọ́n rúbọ sí ère Kénánì, ilẹ̀ náà sì di àìmọ́ fún ẹ̀jẹ̀

Sáàmù 106

Sáàmù 106:34-48