Sáàmù 106:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbi omi Méríbà, wọn bí Ọlọ́run nínú,ohun búburú wá sí orí Mósè nítorí wọn.

Sáàmù 106

Sáàmù 106:29-41