Sáàmù 106:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ibùdó ni wọ́n ṣe ìlara Mósèpẹ̀lú Árónì, ẹni tí ó jẹ́ mímọ́ sí Olúwa.

Sáàmù 106

Sáàmù 106:10-22