Sáàmù 106:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yin Olúwa Ẹ fi ìyìn fún Olúwa, nítorí tí o ṣeun.Ẹ fi ọpẹ́ fún Olúwa nítorí tí ó ṣeun;Nítorí tí ìfẹ́ Rẹ̀ dúró láéláé.

Sáàmù 106

Sáàmù 106:1-3