Sáàmù 104:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nípa ìbáwí Rẹ ni àwọn omi lọ,nípa ohùn àrá Rẹ ni wọ́n sálọ;

Sáàmù 104

Sáàmù 104:6-11