Sáàmù 104:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni òkun yìí tí ó tóbi, tí ó sì ni ìbú,tí ó kún fún àwọn ẹ̀dá alààyè ní ìṣàlẹ̀ láìníyeohun alàyè tí tóbi àti kékeré.

Sáàmù 104

Sáàmù 104:18-33