Ó mú kí koríko hù jáde fún àwọn ẹranko láti jẹàti àwọn ewébẹ fún ènìyàn láti lòkí ó le mú oúnjẹ jáde láti ilẹ̀ wá: