Sáàmù 103:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yin Olúwa, gbogbo iṣẹ́ Rẹ̀ níibi gbogbo ìjọba Rẹ̀.Yin Olúwa, ìwọ ọkàn mi.

Sáàmù 103

Sáàmù 103:13-22