Sáàmù 103:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun kì í ṣe sí wá gẹ́gẹ́ bí ẹ̀ṣẹ̀ wabẹ́ẹ̀ ni kì í san-án fún wa gẹ́gẹ́bí àìṣedédé wa.

Sáàmù 103

Sáàmù 103:6-20