Sáàmù 102:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi jẹ eérú gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ mi, èmi si da ohun mímu mi pọ̀ pẹ̀lú omíjé.

Sáàmù 102

Sáàmù 102:5-10