Sáàmù 102:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe pa ojú Rẹ mọ́ kúrò lọ́dọ̀ miní ọjọ́ tí èmi wà nínú ìpọ́njú.Dẹ etí Rẹ sí mi;nígbà tí mo bá pè, dámi lóhùn kíákíá.

Sáàmù 102

Sáàmù 102:1-3