Sáàmù 102:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Torí tí Olúwa yóò gbé Síónì ró, yóò farahàn nínú ògo Rẹ̀.

Sáàmù 102

Sáàmù 102:8-21