Sáàmù 102:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ó dìde ìwọ o sì ṣàánú fún Síónì,nítorí ìgbà àti ṣe ojú rere sí i;àkókò náà ti dé.

Sáàmù 102

Sáàmù 102:7-15