Sáàmù 101:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò máa rin ìrìn mi pẹ̀lú ọgbọ́n láìlẹ́sẹ̀, ìgbà wo ni ìwọ yóò wá sí ọ̀dọ̀ mi?Èmi yóò máa rìn ní ilé mi pẹ̀lú àyà pípé.

Sáàmù 101

Sáàmù 101:1-7