Sáàmù 100:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ lọ sí ẹnu ọ̀nà Rẹ̀ pẹlú ọpẹ́àti sí àgbàlá Rẹ̀ pẹ̀lú ìyìn;ẹ fi ọpẹ́ àti ìyìn fún orúkọ Rẹ̀.

Sáàmù 100

Sáàmù 100:1-5