Sáàmù 10:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀nà Rẹ̀ ń gún régé nígbà gbogbo;òun ń gbéraga, òfin Rẹ sì jìnnà sí i;òun kẹ́gàn àwọn ọ̀ta Rẹ̀.

Sáàmù 10

Sáàmù 10:1-8