Sáàmù 10:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dìde, Olúwa! Gbé ọwọ́ Rẹ̀ sókè, Ọlọ́run.Má ṣe gbàgbé àwọn olùpọ́njú.

Sáàmù 10

Sáàmù 10:5-13