Rúùtù 4:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, nígbà tí ọkùnrin náà sọ fún Bóásì wí pé, “Ìwọ rà á fúnràrẹ,” ó yọ bàtà rẹ̀ kúrò ní ẹsẹ̀ rẹ̀.

Rúùtù 4

Rúùtù 4:1-14