Rúùtù 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn obìnrin sì wí fún Náómì pé, “Ìyìn ni fún Olúwa tí kò fi ọ sílẹ̀ ní òní yìí láìní ìbátan, Olùràpadà. Kí ọmọ náà di olókìkí ní Ísírẹ́lì.

Rúùtù 4

Rúùtù 4:8-20