Rúùtù 3:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Náómì sì wí fún-un pé, “Dúró, ọmọbìnrin mi títí tí ìwọ yóò fi mọ bí ohun gbogbo yóò ti rí. Nítorí pé ọkùnrin náà kò ní sinmi títí tí ọ̀rọ̀ náà yóò fi yanjú lónìí.”

Rúùtù 3

Rúùtù 3:13-18