Rúùtù 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Bóásì dé láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù tí ó sì kí àwọn olùkórè wí pé, “Kí Olúwa wà pẹ̀lú yín.”Wọ́n sì dá a lóhùn padà pé, “Kí Olúwa bùkún fún ọ.”

Rúùtù 2

Rúùtù 2:1-10