Rúùtù 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rúùtù sì jáde lọ láti ṣa ọkà tí àwọn olùkórè fi sílẹ̀ lẹ́yìn wọn. Ó wá jẹ́ wí pé inú oko Bóásì tí ó ti ìdílé Elimélékì wá ni ó lọ láé mọ̀ ọ́ mọ̀.

Rúùtù 2

Rúùtù 2:1-7