Rúùtù 2:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Náómì sì sọ fún Rúùtù, ìyàwó ọmọ rẹ̀ pé, “Ìbá dára bí ó bá le bá àwọn ìránṣẹ́-bìnrin rẹ̀ ṣiṣẹ́. Nítorí pé wọ́n le è dà ọ́ láàmú bí o bá lọ sí oko ẹlòmíràn.”

Rúùtù 2

Rúùtù 2:15-23