Rúùtù 2:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rúùtù, ará Móábù sì wí pé, “Ju gbogbo rẹ̀ lọ, ó sọ fún mi pé, ‘Kí ń máa ṣa ọkà pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ òun, títí wọn yóò fi parí ìkórè.’ ”

Rúùtù 2

Rúùtù 2:14-22