Rúùtù 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí Olúwa kí ó san ẹ̀san ohun tí o ṣe fún ọ. Kí o sì gba èrè kíkún láti ọ̀dọ̀ Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì abẹ́ ìyẹ́ ẹni tí ìwọ sá wá fún ààbò.”

Rúùtù 2

Rúùtù 2:4-22