Rúùtù 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rúùtù wólẹ̀, ó sì wí fún Bóásì pé, “Èéṣe tí èmi fi bá ojúrere rẹ pàdé tó báyìí, tí o sì kíyèsí mi, èmi àjèjì àti àlejò?”

Rúùtù 2

Rúùtù 2:7-20