Róòmù 8:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa sì mọ̀ pé ohun gbogbo ni ó ń siṣẹ́ pọ̀ sí rere fún àwọn tí ó fẹ́ Ọlọ́run, àní fún àwọn ẹni tí a pè gẹ́gẹ́ bí ìpinnu rẹ̀.

Róòmù 8

Róòmù 8:23-35