Róòmù 7:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì ti wà láàyè láìsí òfin nígbà kan rí; ṣùgbọ́n nígbà tí òfin dé, ẹ̀ṣẹ̀ sọjí èmi sì kú.

Róòmù 7

Róòmù 7:4-10