Róòmù 7:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ti ipa òfin rí àyè láti tàn mí jẹ, ó sì ti ipa òfin se ikú pa mi.

Róòmù 7

Róòmù 7:4-15