Róòmù 6:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pé, kí ni ìyọrísí rẹ̀? Dájúdájú àbájáde rẹ̀ kò dára. Níwọ̀n ìgbà tí ojú ń tì ọ́ nísinsìnyìí láti ronu nípa àwọn wọ̀n-ọn-nì tí o ti máa ń sọ nítorí gbogbo wọn yọrí sí ìparun ayérayé.

Róòmù 6

Róòmù 6:15-22