Róòmù 5:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kì í sì ṣe bẹ́ẹ̀ nìkan, ṣùgbọ́n àwa tún ń ṣògo nínú ìjìyà pẹ̀lú: bí a ti mọ̀ pé ìjìyà ń sisẹ́ sùúrù;

Róòmù 5

Róòmù 5:1-5