Róòmù 4:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wí pé, “Ìbùkún ni fún àwọnẹni tí a dárí ìrékọjá wọn jì,tí a sì bo ẹ̀ṣẹ̀ wọn mọ́lẹ̀.

Róòmù 4

Róòmù 4:1-16