Róòmù 4:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò fi àìgbàgbọ́ ṣiyèméjì nípa ìlérí Ọlọ́run; ṣùgbọ́n ó lágbára sí i nínú ìgbàgbọ́ bí ó ti fi ògo fún Ọlọ́run;

Róòmù 4

Róòmù 4:17-25