Róòmù 3:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àní òdodo Ọlọ́run nípa ìgbàgbọ́ nínú Jésù Kírísítì, sí gbogbo ènìyàn àti gbogbo àwọn tí ó gbàgbọ́: nítorí tí kò sí ìyàtọ̀:

Róòmù 3

Róòmù 3:21-23