Róòmù 3:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa sì mọ̀ pé ohunkóhun tí òfin bá wí, ó ń wí fún àwọn tí ó wà lábẹ́ òfin: kí gbogbo ẹnu bá à lè dákẹ́ àti kí a lè mú gbogbo aráyé wá sábẹ́ ìdájọ́ Ọlọ́run.

Róòmù 3

Róòmù 3:18-26