Róòmù 2:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìpọ́njú àti ìrora, yóò wà lórí olúkúlùkù ọkàn ènìyàn tí ń hùwà ibi: ti Júù ṣáájú, àti àwọn aláìkọlà pẹ̀lú;

Róòmù 2

Róòmù 2:1-19