Róòmù 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tàbí ìwọ ń gàn ọrọ̀ oore àti ìpamọ́ra àti sùúrù rẹ̀? Ìwọ kò ha mọ̀ pé oore Ọlọ́run ni ó ń fà ọ́ lọ sì ìrònúpìwàdà?

Róòmù 2

Róòmù 2:1-6